@josh_eneji: how to recite psalm 70 in yoruba (orin dafidi 70). It is a plea for God to act as the covenant God of the faith tradition.ORIN DAFIDI 70:1-5 YCE [1] Ọlọrun, dákun, gbà mí, yára, OLUWA, ràn mí lọ́wọ́. [2] Jẹ́ kí ojú ti gbogbo àwọn tí wọn fẹ́ gba ẹ̀mí mi kí ìdàrúdàpọ̀ bá wọn; jẹ́ kí á lé àwọn tí ń wá ìpalára mi pada sẹ́yìn, kí wọn sì tẹ́. [3] Jẹ́ kí jìnnìjìnnì bo àwọn tí ń yọ̀ mí, tí ń ṣe jàgínní mi; kí wọn sì gba èrè ìtìjú. [4] Kí gbogbo àwọn tí ń wá ọ máa yọ̀ nítorí rẹ, kí inú wọn sì máa dùn, kí àwọn tí ó fẹ́ràn ìgbàlà rẹ máa wí nígbà gbogbo pé, “Ọlọrun tóbi!” [5] Ṣugbọn ní tèmi, olùpọ́njú ati aláìní ni mí, yára wá sọ́dọ̀ mi, Ọlọrun! Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi ati olùgbàlà mi, má pẹ́ OLÚWA. #psalms #sunday #yorubatiktok #orindafidi #psalm70 #nigeriantiktok🇳🇬 #fyp #bibleverse #creatorsearchinsights #God #jesus #millionviews

josh_eneji
josh_eneji
Open In TikTok:
Region: NG
Sunday 09 March 2025 07:46:10 GMT
70166
2957
184
1810

Music

Download

Comments

gloris.beaut.empi
HAIR, NAILS AND LASHES IN ABK :
Amin
2025-07-17 10:56:24
1
felix.adeleke
Felix Adeleke :
Amin loruko jesu
2025-03-10 23:29:48
1
bolanlesobowale
Bolanle Sobowale :
Amin
2025-06-01 02:14:59
1
jinboydonna
Jinlevel🎶❤️ :
Amin
2025-03-09 15:09:59
1
user9311610761902
simple life :
Amin 🙏
2025-03-13 01:44:23
1
ayoni936
AYONI🦋 :
Amin
2025-03-10 13:03:47
1
user1011564744899
user1011564744899 Olawale :
Aaaaamin jeeesu
2025-03-10 17:00:36
2
herdukeh24
🦋Ewa_tomi_lola🦚 :
Amin loruko jesu
2025-03-09 09:32:12
1
akinyemi3115466969
TennyGold :
Amen Amen Amen
2025-03-10 14:40:32
1
iremide2840
Iremide 🥰 :
Amen 🙏
2025-03-09 08:14:22
1
nannymoney3
Nanny :
Amin 🙏🙏🙏🙏🙏🙏🙏
2025-03-10 18:40:28
1
ayobami.adeshina4
Ayobami Adeshina :
Amin
2025-05-07 23:29:05
1
olabisi.beauty4
olabisi beauty :
amin amin amin loruko jesu 🙏🙏🙏🙏🙏
2025-03-09 10:08:27
1
obarokayode
obarokayode :
Amen
2025-03-09 11:19:55
1
user31959952534527
MUMCY OLUWATIRESIMI :
Amin Amin Amin Amin Amin Amin Amin Jesu
2025-03-10 12:59:54
2
oluwaremilekun755
oluwaremilekun :
AMEN
2025-03-09 08:47:52
2
samautomobile123
🦺Sam Automobile🦺 :
Amin jesu 🤲🔥
2025-03-10 18:56:03
2
mojolaanuoluwa1
mojolaanuoluwa1 :
Amin jesu
2025-03-09 12:12:35
1
seyila_247
Prince Owonikoko Sheyi Akinwumi :
Amin
2025-03-09 14:25:47
3
daramola82
phamous 82 :
AMEN 🙏🙏🙏🙏🙏 In Jesus name
2025-03-10 14:50:37
2
kikelomo.labake
ROTIMI KIKELOMO :
Amin
2025-03-09 13:09:45
1
oluwakemimoseseko0
Olori Eko 1 :
amin
2025-03-09 09:05:17
1
opeyemiegbelekead
mhiz opeyemi :
amin Jesu
2025-03-09 08:41:37
1
adeoriokin178
ADEORIOKIN1 :
Amen 🙏
2025-03-09 14:17:44
1
userawuni562
Babalola Bolanle :
Amin jesu Christ
2025-03-10 16:36:33
1
To see more videos from user @josh_eneji, please go to the Tikwm homepage.

Other Videos

𝐋𝐨𝐅𝐢 𝐑𝐞𝐦𝐢𝐱 🦋 𝐁𝐚𝐧𝐠𝐥𝐚𝐝𝐞𝐬𝐡 𝐦𝐚𝐲 🎬 𝐧𝐞𝐯𝐞𝐫 𝐟𝐮𝐥𝐥𝐲 𝐮𝐧𝐝𝐞𝐫𝐬𝐭𝐚𝐧𝐝 𝐡𝐨𝐰 𝐦𝐮𝐜𝐡 𝐈 𝐥𝐨𝐯𝐞 𝐲𝐨𝐮.
𝐋𝐨𝐅𝐢 𝐑𝐞𝐦𝐢𝐱 🦋 𝐁𝐚𝐧𝐠𝐥𝐚𝐝𝐞𝐬𝐡 𝐦𝐚𝐲 🎬 𝐧𝐞𝐯𝐞𝐫 𝐟𝐮𝐥𝐥𝐲 𝐮𝐧𝐝𝐞𝐫𝐬𝐭𝐚𝐧𝐝 𝐡𝐨𝐰 𝐦𝐮𝐜𝐡 𝐈 𝐥𝐨𝐯𝐞 𝐲𝐨𝐮.".! 🥺 🌸𝐋𝐨𝐅𝐢 𝐑𝐞𝐦𝐢𝐱 🦋 𝐁𝐚𝐧𝐠𝐥𝐚𝐝𝐞𝐬𝐡 🎵 🎧𝐥𝐨𝐟𝐢 𝐀𝐩𝐨𝐧🎧 𝐯𝐨𝐢𝐜𝐞𝐟𝐨𝐫𝐲𝐨 𝐌𝐚𝐲𝐛𝐞 𝐈 𝐰𝐫𝐢𝐭𝐞 𝐲𝐨𝐮𝐫 𝐧𝐚𝐦𝐞 𝐢𝐧 𝐦𝐲 𝐛𝐫𝐞𝐚𝐭𝐡, 𝐁𝐮𝐭 𝐲𝐨𝐮 𝐜𝐚𝐧'𝐭 𝐡𝐞𝐚𝐫 𝐢𝐭."!! 𝐀𝐥𝐥 𝐈 𝐜𝐚𝐧 𝐬𝐚𝐲 𝐢𝐬 𝐭𝐡𝐚𝐭 𝐲𝐨𝐮 𝐚𝐫𝐞 𝐭𝐡𝐞 𝐫𝐞𝐚𝐬𝐨𝐧 𝐟𝐨𝐫 𝐦𝐲 𝐡𝐚𝐩𝐩𝐢𝐧𝐞𝐬𝐬, 𝐲𝐨𝐮 𝐚𝐫𝐞 𝐭𝐡𝐞 𝐦𝐚𝐧 𝐛𝐞𝐡𝐢𝐧𝐝 𝐦𝐲 𝐬𝐦𝐢𝐥𝐞.💌 🎬 𝐖𝐢𝐭𝐡𝐨𝐮𝐭 𝐲𝐨𝐮, 𝐦𝐲 𝐝𝐚𝐲𝐬 𝐬𝐞𝐞𝐦 𝐞𝐦𝐩𝐭𝐲. 𝐒𝐨𝐦𝐞𝐭𝐡𝐢𝐧𝐠 𝐬𝐞𝐞𝐦𝐬 𝐭𝐨 𝐛𝐞 𝐠𝐨𝐢𝐧𝐠 📵 𝐰𝐫𝐨𝐧𝐠 𝐚𝐥𝐥 𝐭𝐡𝐞 𝐭𝐢𝐦𝐞.".! 𝐘𝐨𝐮 𝐚𝐫𝐞 𝐦𝐲 𝐝𝐫𝐞𝐚𝐦, 𝐲𝐨𝐮 🌿 𝐚𝐫𝐞 𝐦𝐲 𝐟𝐞𝐞𝐥𝐢𝐧𝐠 𝐚𝐧𝐝 𝐦𝐨𝐬𝐭 𝐢𝐦𝐩𝐨𝐫𝐭𝐚𝐧𝐭𝐥𝐲 𝐲𝐨𝐮 𝐚𝐫𝐞 𝐦𝐲 😔 𝐩𝐞𝐚𝐜𝐞. 𝐈 𝐟𝐞𝐞𝐥 𝐲𝐨𝐮 𝐞𝐯𝐞𝐫𝐲 𝐦𝐨𝐦𝐞𝐧𝐭, 𝐞𝐯𝐞𝐧 𝐢𝐟 𝐲𝐨𝐮 𝐚𝐫𝐞 𝐧𝐨𝐭 𝐛𝐲 𝐲𝐨𝐮𝐫 𝐬𝐢𝐝𝐞. 𝐘𝐨𝐮 𝐦𝐚𝐲 𝐛𝐞 𝐟𝐚𝐫 𝐚𝐰𝐚𝐲, 𝐛𝐮𝐭 𝐦𝐲 𝐥𝐨𝐯𝐞 𝐚𝐥𝐰𝐚𝐲𝐬 𝐬𝐰𝐢𝐫𝐥𝐬 𝐚𝐫𝐨𝐮𝐧𝐝 𝐲𝐨𝐮 𝐥𝐢𝐤𝐞 🧾 𝐚 𝐬𝐡𝐚𝐝𝐨𝐰..! 𝐀𝐬 𝐥𝐨𝐧𝐠 𝐚𝐬 𝐈 𝐥𝐢𝐯𝐞, 𝐈 𝐰𝐚𝐧𝐭 𝐲𝐨𝐮 𝐭𝐨 𝐛𝐞 𝐡𝐚𝐩𝐩𝐲... 𝐐𝐮𝐢𝐞𝐭𝐥𝐲, 𝐪𝐮𝐢𝐞𝐭𝐥𝐲.".! 𝐉𝐮𝐬𝐭 𝐟𝐨𝐫 𝐲𝐨𝐮..!! 🥺😅❤️#lofi_apon #aveeplayer #foryoupage #viralvideo #আইডিতে_view_like_আসে_না😪😪😪

About