Ade :
oba oluwa lo ni dédé, Alawura mi lo sogo e ooo. Eni emi e ba si wa,2xe ka ma sope ko le nílári mo. Ikan naa ni kaun, kaunkaun ni o da o 2xe., kaunkaeni ni o da ooo, ba se, eni base, eni base, enibase kiyo o dunbe, ẹnikan o gnodo le ninu egbe. aahh mo tun gbekan de, sonmori area yi o, sonori area yi o. a o ni wain, a o níwájú, a o níwájú tí a o je ti, a o ni pàdé ohun ti o je wa.
Alawura o ni o sere fun wa, Alawurbi o ni o sere fun wa, ọba to nile ayé, alawurabi o ni o sere fun wa. ahh oba to nile ayé, iba Alawurabi o ni o sere fun wa
2026-10-19 08:02:27