@qdoabd1: #الكوافير #قدوري_المزين #قدوري_الجنابي #حلاقتك_نصف_اناقتك💈 #حلاقة180درجة

قدوري المميز
قدوري المميز
Open In TikTok:
Region: IQ
Wednesday 11 February 2026 12:58:03 GMT
1572
79
1
2

Music

Download

Comments

user1912176667332
عمار 👻🤙 :
🥰🥰🥰
2026-02-11 15:17:01
0
To see more videos from user @qdoabd1, please go to the Tikwm homepage.

Other Videos

IRAWO INA ATUPA (SAGITTARIUS)♐️ PART 1 (November 23 - December 22) Olorire ni awon onirawo yi je,  planet tonjoba awon oni irawo yin ni amo si Jupiter 🌔   ni eyi ti amo si  planet 🌔   of mercy,    awon  oni  irawo yi  wa lucky , awon oni irawo yi ma nri anu gba pupo lodo awon eniyan,  afi eyiti ogun idile ba ndalamu nikan loku.  Arinrin ajo ni awon oni irawo yi tori won feran ominira pupo (freedom)  won feran lati ma lo kakiri,  pupo ninu won gan ni irin ajo(traveling) ma ngbe  won kuro ninu ilu ti won ba biwon si losi ilu miran.  Awon oni irawo yi ni igbagbo ninu olohun lori gbogbo isoro ti oba deba won, won ma nfi ti si odo olohun won situn je eda tiko ka nkan kun,  iwa aika  nkan kun ma nfa wahala sinu aye won toripe pupo ninu won ma ni ogun idile ni eyi ti won gbogbodo mu ojuto, ogun idile won ma nni agbara gan, ni eyi ti yio ma fa ijakule ati ifaseyin fun won ni gbogbo ibikibi tiwon ba de.  Iwo ti oba je omo saggitarus, ma gbe family house 🏚 toripe ibe ni ogun aiye yin tin ma nkoko bere.  Awon oni irawo yi won je oloju anu eniyan ti won ma nse anu fun awon eniyan won situn nife awon obi won pupo.  Olokiki eniyan olola eniyan ni awon oni irawo yi je asiwaju eniyan niwon, awon oni irawo yi feran party pupo bi anlo ode ni gbo igba,   won feran lati ma yan ore (friend ) gan ni eyi ti won gbodo sora fun toripe oleda irin ajo aiye won ru.  Awon onirawo yi oju won tutu won situn je eniyan ti iseda won kofe  wahala besitun ni iseda won tako kiwon ma lo ise lile ole fa wahala sinu irin ajo aiye won.  Olopolo pipe ni awon onirawo yi,ogbon ori won bi ti  ijapa ni, opolopo won situn ma npa iro.  Awon oni irawo yi feran nkan meremere, ibinu abiju ati iwa orikunkun poju fun won , ni eyi ti won gbogbo sora fun toripe yio ma fa ifaseyin ati wahala sinu aiye won.  olohun ma ntete sanu won ni aro aiye won, eyiyi ma nje ki won gbagbe lati mu oju to oro aiye won, awon oni irawo yi ko gbodo fi igbinyanju sile ninu irin ajo aiye won, won  situn gbodo mu oju to ogun idile tin nma bawon ja, tori ibi ti awon oni irawo yi nlo ninu aiye jingan, won kogbodo fi igbinyanju sile ninu irin ajo aiye won,  kiwon leba tete de ibi ti won nlo ninu aiye,  toripe pupo ninu won ma nni ogun ota pupa ninu irin ajo won.  Asiri po ni abe irawo yi ti akole sotan iwo ti obafe mo nipa asiri topamo si abe irawore  pelu alaye lekunrere Message me privately.  Osepataki fun gbogbo eniyan lati mo nipa irawo re toripe itosona ni irawo je fun gbogbo eniyan lati letete de ibi ogo re.  Eniyan tikobamo nipa irawo re yio le fun lati le tete de ibi ogore  toripe oluranlowo ni irawo je fun gbogbo eniyan lati le tete de ibi akosejaye re.  Gbogbo irawo kokan  ni won ni eewo ti won,  tio  ye ki won  jina si bena situn ni nkan tio ye  ki won mase ti won fi tete de bi ogo won.   Ti eniyan ba nse nkan totako irawo re abi onfun irawo re ni eewo je  iru eniyan be yio le fun lati tete de ibi ogore toripe gbogbo  irawo kokan ni won ni awon emi ti won ba won  sise  awon emi yi oluranlowo ni won je,  iwo ti oba  tifun won ni eewo je abi o mo  awon nkan toroma irawo re ti ofin wa nse nkan totako irawo re  awon emi yi ma jina sio ti awon emi yi ba siti jinna si eniyan nkan yio  bere sini daru fun  iru eniyan be,  bio se  ogun ko ni sise promise and fail yio situn mada iru eniyan be lamu  iwo ni kiolo se iwadi arare koma ba waiye asan.  Ose pataki fun o  lati lo mo nipa irawo re  kio leba tete ri ona lo.  FUN IBERE TABI IWADI NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE....MESSAGE MI LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA LORI PROFILE MI

About