@juanaventure: snorkeling at #tulangdiotisland💛🌊 #camotes #fyp #philippines2026

juanaventure
juanaventure
Open In TikTok:
Region: PH
Sunday 31 May 2026 05:22:23 GMT
281
11
0
0

Music

Download

Comments

There are no more comments for this video.
To see more videos from user @juanaventure, please go to the Tikwm homepage.

Other Videos

Haaaa! Nkan dee óò!! Àbí irú kí wá leleyi óò!!! Opebe tí jáde rawọ ẹ̀bẹ̀ si ẹyin èèyàn ooo Òṣeré Yorùbá, Yomi King, tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Baba Opebe, ń dojú kọ àìsàn tó ti ń bá a ja fún ohun tó ju ọdún kan lọ bayyi. Ìròyìn tuntun fi hàn pé Baba Opebe ti ṣàbẹ̀wò sí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ilé ìwòsàn láti wá ìtọ́jú, ṣùgbọ́n kò tíì sí àyẹ̀wò tó fi hàn gbangba ohun tó ń fa àìsàn náà. Nínú fídíò kan tí ósere àti olùdarí fíìmù, Kunle Afod, pín lẹ́yìn tó ṣèbẹ̀wò sí Baba Opebe nílé rẹ̀ ní Ibadan, Baba Opebe ṣàlàyé pé àwọn dókítà sọ fún oun pé iye ẹ̀jẹ̀ inú ara oun ti dín kù. Ó ní wọ́n ti fún un ní pints mẹ́rin ẹ̀jẹ̀, ṣùgbọ́n ìlera rẹ̀ kò tíì bọ sípò. Baba Opebe tún sọ pé àìsàn náà ti mú kó kúrò lórí eré fíìmù fún àkókò kan, àti pé ó ti lọ sí ilé ìwòsàn oríṣìíríṣìí láti wá ojútùú sí ìṣòro ìlera náà. Àwọn ìròyìn tó wà nílẹ yìí kò sọ pé dókítà ti jẹ́rìí sí àrùn kan pàtó tó ń fa ìṣòro náà. Nígbà tó ṣe abẹwo sí Baba Opebe, Kunle Afod sọ pé ohun tí òun rí nílé wọn bà ohun lẹ́rù gan-an. Ó sì ké sí àwọn aráàlú, àwọn olólùfẹ́ àti àwọn tó lè ṣe ìrànlọ́wọ́ pé kí wọ́n máa ṣe àtìlẹ́yìn fún àgbà òṣèré náà, nípa ìrànlọ́wọ́ ìṣègùn, owó àti àdúrà.

About