@chifedroladimeji: Eso Pandoro (tí a mọ̀ sí Kigelia africana tàbí Sausage tree ní èdè Gẹ̀ẹ́sì) jẹ́ èso igi kan tí ó ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àǹfààní àti ìwúlò fún ìlera èdìá lọ́kùnrin àti lóbìnrin nínú iṣẹ́ agbégbà nítorí àwọn èròjà àdánidá rẹ̀. Àwọn àgbà rí i gẹ́gẹ́ bí èso tí ó ní agbára láti wo àwọn àìsàn púpọ̀....#tiktok #viral #foryoupage #fypシ #fypppppppppppp