@babalawo.atorise: Tewe tegbo" (Ta ewe, ta egbo) tumọ si lati ta ewe ati gbongbo igi fun iwosan tabi oogun abinibi. Oro yii jẹ owe tabi gbolohun ti a n sọ nigba ti a ba n tẹnumọ pataki oogun ile wa ati bi ẹda kọọkan ṣe ni ọna ti Ọlọrun gba n ṣatunṣe igbesi aye rẹ.....#fyp #foryou #tiktok #viral #fyppppppppppppppppppppppp