@harunha3an: #trending #fyp #growth #daytrader

HarunTrades
HarunTrades
Open In TikTok:
Region: US
Sunday 19 July 2026 17:30:53 GMT
1157
65
2
2

Music

Download

Comments

an2ti1
ant :
holy grind💪
2026-07-20 04:34:54
1
To see more videos from user @harunha3an, please go to the Tikwm homepage.

Other Videos

Oríkì Ìjèbú tó ń mú orí wú bíi Gaàrí ìjèbú. Where in Ijebu land are you from? Let’s connect in the comments below. • Oríkì Ìjẹ̀bú Ìjèbú, ọmọ Alárẹ̀ ọmọ bíbíire é jùú fowórà ọmọ aṣ’àlè jẹ́jẹ́ b’ọni i n’obìnrin,  ọmọ Olúwàbí ẹ̀yin l’ọmọ Olúìwà,  ọmọ Ọbánta,  ọmọ Alárẹ̀ Láani ni ìyá wọn jẹ́ ẹyin lọmọ Láani po póòyè ọmọ Ẹdan Ìyá ẹni ò bí ni kí á máa wá ọlá ọlọ́lá kiri Láani ò bí ni ká lọ rèé ṣe asingba asingba nílé Láani ẹ̀yin l’ọmọ Erelú Ìjèbú tí ń f’ọkọ rẹ̀ jẹ apèènà Ìjèbú l’ọmọ alágẹmọ ò tú yọ̀wọ̀yọ̀wọ̀ Ọmọ b’èpè ò jà mọ́ ma yáa wá oun míì tún ṣe Ẹ̀yin lọmọ ar’ójò joyè ọmọ awíire f’àṣe banu ọmọ olówó joyè méjì pọ̀ Ẹ̀yin lọmọ afánwó, bí ẹ ní f'ọ̀yàngàn,  ọmọ arígbá nlá buwó, ni wọ́n kì yín nílé bàbá tó bíi yín lọ́mọ.  Ọmọ ẹlẹ́yìnkùlé àdé ‘wúre ni yín,  òòṣà jẹ́ ń dàbí onílé yìí,  ni wọ́n fi ń kí Ìjèbú wípé:  Ìgbá Ìjèbú, owó ni,  Kòkò Ìjèbú, owó ni Awọ Ìjèbú, owó ni Ọmọdé Ìjèbú, owó  Àgbà Ìjèbú, owó Kúkúrú Ìjèbú, owó Gíga Ìjèbú, owó Pupa Ìjèbú, owó Dúdú Ìjèbú nkọ́, owó Gbogbo ara kìkì owó Òun ni Ìjèbú Ẹ̀yin l’ọmọ a fìdí p’ọ̀tẹ̀ mọlẹ̀ Iṣu mẹ́fà sáa ni iṣu Ìjèbú Wọ́n ta méjì, wọ́n jẹ méjì síkùn ara wọn. Óní òòṣà tí wọ́n n fi méjì tó kù bọ Ẹ̀yin lọmọ òun ṣeni ọ̀yọ̀yọ̀ n yọ̀ Ọ̀yọ̀yọ̀ dákún, oò bá má yọ̀ mọ́ Òun ṣe ni ò ní leè pa'ni Ọmọ ọlọ́pẹ kan ò jẹ́gẹ́ ti rí gẹ́ Ẹ̀yin lọmọ ọlọ́pẹ kan ò jẹ́gẹ́ ti ri gẹ̀ Kò ga jù, kò kúrú Ó ń fọwọ́ imọ̀ gbalẹ̀ gẹ̀ẹ̀rẹ̀gẹ̀ Ayé gba Ìjèbú ó hun ẹní rẹ̀ wíníwíní Àyé gba Ìjèbú ó hun ẹní rẹ̀ wìnìwìnì Ayé gbọmọ ọ̀gbánrángánlùdá ó fi ẹní rẹ̀ tó kù, ó fi ṣ’ọdún alágẹmọ Àwọn lọmọ dúdú ilé ò mọ ọbẹ̀ se Èyí pupa tí ó mọ ọbẹ̀ se, lọ́jọ́ táa délé, a ò báa nílé Ọmọ adìẹ g’orókùn, ó pò lele Ara ò rokùn, okùn mì gìgì, bẹ́ẹ̀ ni ara ọ̀ rọ Adìẹ Ẹ̀yin lọmọ onígbó, mádè mádè Ọmọ onígbó má wọ̀ ma wọ̀ Àjòjiì tí ó bá ṣèṣì wọ ‘gbóorò, a di ẹni ẹbọra nílé bàbá tó bíi yín l’ọmọ  Wọn kì í mú eégún wọ ‘gbóorò  Irán bàbá yín ló mú eégún wọ igbó Rẹ́mọ Ọmọ mo rẹ́yẹ mámà r’òkò Mo r’òkò tán, ẹyẹ́ ti lọ Ọmọ mo n’íṣu nílé, má mà r’ọ̀bẹ Ọ̀bẹ tó wà ní ilé yí ò pọ́n nílé bàbá tó bíi yín l’ọmọ Ẹ nlè o. Ìjèbú, ọmọ Èrenìwà. #ijebu #orikiijebu #ojudeoba #yorubadun

About