@bayonlebalogun: OLUWA li Oluṣọ-agutan mi; emi kì yio ṣe alaini. O mu mi dubulẹ ninu papa-oko tutù; o mu mi lọ si iha omi didakẹ rọ́rọ́. O tù ọkàn mi lara; o mu mi lọ nipa ọ̀na ododo nitori orukọ rẹ̀. Nitõtọ, bi mo tilẹ nrìn larin afonifoji ojiji ikú, emi kì yio bẹ̀ru ibi kan; nitori ti Iwọ pẹlu mi; ọgọ rẹ ati ọpá rẹ nwọn ntù mi ninu. Iwọ tẹ́ tabili onjẹ silẹ niwaju mi li oju awọn ọta mi; iwọ dà ororo si mi li ori; ago mi si kún akúnwọsilẹ. Nitotọ, ire ati ãnu ni yio ma tọ̀ mi lẹhin li ọjọ aiye mi gbogbo; emi o si ma gbe inu ile Oluwa lailai. #psalms23

Omobayonle💕
Omobayonle💕
Open In TikTok:
Region: CA
Monday 20 July 2026 04:32:40 GMT
255
40
1
4

Music

Download

Comments

arolejubaband
AROLEJUBA BAND :
❤️❤️❤️
2026-07-20 09:11:06
0
To see more videos from user @bayonlebalogun, please go to the Tikwm homepage.

Other Videos


About