@baba.olohun.lagb001: OGUN IFERAN ONI ADO TI AFI SO OLOLUFE MEJI PAPO. Eyin eyan mi ejowo ejekia gbiyanju ise iferan kekere yii wo, ise yii le jo bi ere loju sugbon danwo lobi iya okere… Eo dupe lowo OBA TIO SEDA EWE ATI EGBO… ISE NAA RE Ao ko oruko awon mejeji sinu paper funfun kan Ewe ojuoro Ao wa alangba Ako ati Abo (1) Ewe bomubomu (5) Ewe Akoko (5) Ewe ominsinmisin (oloju musu) Orongbo (5) Iye adie Ako ati Abo (2) Atare aja Odindi (1) Ao jo gbogbo awon nkan yii papo ninu ape ijogun, tia bati jo tan ao ro ebu yii sinu ADO kan ao fi nkan di lori… Ao wa lo rii ADO naa si eti odo tio san dada. Oju ese tia bati rii ADO yii mole tan naa ni ise ti bere ti ife eni toba se ise yii oti wa lokan eni naa ti ara kosi ni ro eni naa lai jepe eyin mejeji fi oju kan ara yin… Ema je kin royin ise yii pupo ju, Danwo kio fun ile labo. Akiyesi Enikankan ko gbodo rii wa tia ba lo rii ADO yii mole, Aijebe ise yii koni dahun. Anfani wa fun eni tiko bale se ise na fun ara re, Ale bayin se. call or WhatsApp 08020734790