@oderemomegatradefair: Ẹ̀yin ara Ọ̀dẹ̀, àti gbogbo ará ìlú tó yí wa ká, ẹ má ṣe gbàgbé o! ❤️ Ode-Remo Mega Trade Fair 2026 ti dé báyìí. Ẹ wá bá wa raja, ẹ sì gbádùn: 🛍️ Àwọn ọja tó dára ní iye tó rọrùn. 🎁 Àwọn ẹ̀bùn raffle tó ju 150 lọ. 💰 ₦30,000 CASH fún One Lucky Shopper. 🎉 Ebun láti ọ̀dọ̀ àwọn Olutaja. ✨ Ohun gbogbo te fẹ́ràn ni yóò wà níbẹ̀. Ẹ mú ọkọ yín, ìyàwó yín, àwọn ọmọ yín, ẹbí àti ọ̀rẹ́ yín wá. Ẹ jẹ́ ká ṣe ìtàn pẹ̀lú wa ní maiden edition yìí. 📅 29th, 30th & 31st July 2026 🕘 9:00 AM – 6:00 PM Daily 📍 Opposite AUD Nursery & Primary School Field, Ode-Remo Ẹ wá bá wa raja, ẹ sì jẹ́ ká fi ayọ̀ kí yín. A ń retí yín! ❤️🛍️ #OdeRemoMegaTradeFair #ShopConnectGrow #viralvideo #SupportLocalBusinesses #TradeFair2026 @ᴏᴅᴇ ʀᴇᴍᴏ ᴄᴏᴍᴍᴜɴɪᴛʏ @OmO-Remo ESOE T.V📺 @REMO YOUNG ENTREPRENEURS @Big Bewa @Everything __By__Senni @Herb Vendor inSapaade/Gaposa🌿 @SIGNOUT VENDOR IN SAAPADE/OGUN @OMO LAFOSE @Maryjane luxury saapade vendor @Debbie’s hair care @KIDS STORE IN OGUN STATE👗 @MAKEUPANDHAIRSTYLIST@SAAPADE @bigsolution88 @nailsbyfancy_nancy|Aesthetics @Everything by limah✨🛍️

ODEREMOMEGATRADEFAIR
ODEREMOMEGATRADEFAIR
Open In TikTok:
Region: NG
Saturday 25 July 2026 18:41:14 GMT
137
35
1
15

Music

Download

Comments

ayomidesuprise1
SIGNOUT VENDOR IN SAAPADE/OGUN :
❤️❤️❤️
2026-07-25 19:51:34
1
To see more videos from user @oderemomegatradefair, please go to the Tikwm homepage.

Other Videos


About