Afi ki olorun tete boju wole lati sanu mi sasa ni eni ti ko mo mi ni abule ijoko titi de ori olode mo ma ji ni dede ago merin idaji lati lo gba bread mo tu wo Jo mo gba shop mobere sin ta worobo pelu gbogbo iyanju mi na ole lo kolo ni sept 19 olorun nibo ni kin ti bere writing this with tear I need help