@ifayemi289: Wíwẹ egbò: Sísọ omi rẹ̀ loju egbò tabi lilo oje rẹ̀ n ràn lọ́wọ́ láti jẹ́ kí egbò yára sán.Ìrọ̀wọ́ ninu ara: Omi rẹ̀ tí a bá bọ̀ tabi tí a gbo máa n dín rorun tabi ríro ara kù.Ìtọ́jú ibà tabi stroke: Ninu eto agbò ibile, wọ́n máa n da pọ̀ mọ́ àwọn ewé yòókù láti fi ṣe àgbo fún ẹni tí ibà n sìn tàbí tí ó ní àrùn rọpárọsẹ̀ (stroke).#italy #fyp #france🇫🇷 #viral #tiktok