@jp.olgbn.ay: Ìjàpá ti wọ wahalà tó ju ti tẹ́lẹ̀ lọ! 😂🐢😱 Ọba ń wá a, ṣùgbọ́n Ìjàpá tún dá irọ́ tuntun sílẹ̀ pé òun lóyún 😂. Nígbà tó ń sá fún àṣẹ Ọba, ìkòkò náà ṣi ń pe orúkọ rẹ… “ÌJÀPÁÁÁ!” 😨 Ṣé Ìjàpá máa bọ́ lọ́wọ́ Ọba? Kí ló dé tí ìkòkò náà fi mọ orúkọ rẹ? 👀 Ẹ wo part 5 dé òpin, ẹ sì sọ ohun tí ẹ rò pé ó máa ṣẹlẹ̀ #ijapaologbonaye #ijapameta #yorubastoriess #yorubacomedymovies #yorubafolktale