@cacmiraclecentreadoekiti: 🎶🔥 AYANFE — Ẹ JẸ́ KÁ MÚRA SÍLẸ̀! 🔥🎶 Jésù ń bọ̀! Ẹ jẹ́ ká tún múra sílẹ̀! 🙏🏽🕊️ Ẹ jẹ́ ká fi gbogbo ọkàn wa sin Ọlọ́run, ká sì máa gbé ìgbé ayé tó yẹ fún àwọn ọmọ Ọlọ́run. ❤️ 👑 The King is coming! 🔥 Let every heart be ready! #Ayanfe #JesusIsComing #MuraSile #CAC #ChildrensAnniversary @Hojay~star