@chife.eyekori: Ewu púpọ̀ wà nínú lílo oògùn ojú àbáláyé tàbí oògùn tí kò kọjá láti ọwọ́ dokita, nítorí ojú jẹ́ ẹ̀yà ara tó rọrùn láti bàjẹ́. Bí ojú rẹ bá ń ríran báíbáí (blurry vision), ohun tótọ́ ati èyí tó daju jùlọ ni láti rí Dokita Ojú (Ophthalmologist tàbí Optometrist) fún àyẹ̀wò tó múná dóko. Àwọn nǹkan tó máa ń fa ojú báíbáí le dálé oríṣiríṣi nǹkan bíi:...#viral #tiktok #fyp #fyppppppppppppppppppppppp #fypシ