@ifkold.iflr5: ẸTU ỌLA CONNECTION Akọ ati Abo ẹyẹ ẹga Owo ẹyọ 9 Ewe ọla Ewe sawerepepe Odidi atare 1 Ẹ ko gbogbo Eroja yi Sinu fitila oloju mẹrindinlogun 16 Inu rẹ lao ti jọ Inu rẹ lao ti lọ Tabi ki ẹ gbe ọlọ Sori aga ki ẹ wa lọ Ẹtu yi kuna daadaa Lori ọlọ ti agbe sori Aga nio Lẹyin na ẹ da ẹtu yẹn Pada sinu fitila yẹn Ẹ gbe pamọ si aye ọwọ Ẹ mafi miliki lo laraarọ AO TUN MỌ AWỌN ẸNIA GIDI SI ỌRỌ AJE WA YIO SI MA LỌ SI WA JU. ẸTU GIDI NI.. KOJU BAYẸN LỌ IRE O ✌🏽🤍 ‎ ‎ ‎ ‎

Ifákoládé Ifálérè
Ifákoládé Ifálérè
Open In TikTok:
Region: NG
Sunday 20 September 2026 12:36:47 GMT
1679
135
9
28

Music

Download

Comments

colonial91
COLONIAL :
thanks u sir
2026-09-22 13:58:41
1
toheebadegbenro39
Toshibo 6,9 :
thanks sir
2026-09-22 06:21:25
1
olawise741
Horlawise1047 :
esen Baba🙏
2026-09-22 09:36:56
1
osunkemi.akinyemi
osunkemi akinyemi :
ire oo
2026-09-20 20:52:35
1
alhajiismo
omo odo agba :
❤️❤️❤️
2026-09-20 16:34:13
1
To see more videos from user @ifkold.iflr5, please go to the Tikwm homepage.

Other Videos


About