Johnson ( 1 ) :
Wayanrin kowo si, ide lapa, ide lese, Obirinpi, Arogba Aso, Imobale, Omimi, Okiki, Amowomaro Orere ooooooo, Yeye Onimo ooooo, Iya mi Ewuji ooo, Alagbolodo ooo, Abimo madanale, Iwo ni mo n kesi ooo, Eri Olomo yoyo, Oladekoju ooo Eri ooo, Ota ooo, Ide ooo, Edan ooo, Agba ooo Irumole ooo, Omi ooo, Awuraolu Onile Ibu ooo, Amawomaro O ma ku Ola, Yeye Kare Olowo Ide, Yeye de eee, Ibi gbogbo Lona, Ladekoju, Ibi gbogbo Lona, Ewuji ma de ooo, Ibi gbogbo Lona
Eepa Omi ooo !!! 💕💕💕
2026-09-22 23:32:03