@ajibla.kanlm.karni: Ìròyìn gbígbóná jànjàn! 🔥 Gẹgẹ bí àti ṣe rí ì, èyí ni ìròyìn tí a tún rígbọ o nípa ètò ìdìbò iyàn sípò ààrẹ ti ọdún 2027. Ẹ jọwọ ẹ farabalẹ ká jọ gbọ bí ọrọ náa ṣe lọ, kí ẹ sì jẹ́ kí a mọ èrò ti yín náa nípa èyí? #karenibarin1tv #iroyin2027 #atiku #tinubu