@ifkold.iflr5: ASEJẸ ABAMODA OWO Ewe Abamoda tutu 16 Isasun Asejẹ Tuntun Ẹyin Agric 4 Ẹ ma daba owo Pẹlu adura si, bi a base n ja ewe yi Ẹ ko ewe mẹjọ tẹlẹ Ẹ ma kọ oju Ewe na Soke ninu isasun nio Ẹ wa to ẹyin mẹrin 4 si Ẹ wa ko ewe mẹjọ toku Bo ewe yi lelori mọlẹ. Ẹ ma da oju ewe yẹn bo Ẹyin yẹn mọlẹ. Kosi omi nibẹ o Ewe yi ni yio se jina Ẹ wa sọ sori osuka Ẹ se adua si daada Ẹ bo ẹyin yi jẹ Lẹyin na gbogbo epo eyin yi ati ewe yi Ẹ ko soju ọlọ Tabi ki ẹ jo papọ Ẹ gun ẹtu yi mo ọsẹ Tabi ki a ma lo ẹtu Yẹn larọ pẹlu milk Tabi ọti. ‎ ‎KOJU BAYẸN LỌ IRE O ✌🏽🤍 ‎ ‎

Ifákoládé Ifálérè
Ifákoládé Ifálérè
Open In TikTok:
Region: NG
Saturday 26 September 2026 21:48:07 GMT
3735
260
8
25

Music

Download

Comments

temitopejaiyesim9
Temitope Jaiyesimi :
God blessed you sir
2026-09-30 17:03:47
1
reginakkjenner
Reginakkjenner :
thank you sir
2026-09-27 20:17:42
1
olaide0147
Worldbest07 :
Thank you sir Ewe a ma je ooooooo
2026-09-27 21:39:59
1
julius.ogungbemi
Julius Ogungbemi :
adupe pupo sir
2026-09-27 16:14:56
1
salaurabiubabatun
salaurabiubabatun :
Thank
2026-09-27 19:19:58
1
popcy.farhan
Your jigolo odobs sugar boy :
tested confirm
2026-09-28 17:34:21
1
banouyininoussa
banouyininoussa@gmail :
🥰🥰🥰
2026-09-27 12:50:37
1
olaniyiakanni70
Neyo :
🥰🥰🥰
2026-09-27 14:42:30
0
To see more videos from user @ifkold.iflr5, please go to the Tikwm homepage.

Other Videos


About