Iranlowo re jeko do'ri mi 2x
Tori Ile aye ko se gbe lai si iranlowo re
2026-09-28 10:58:32
7
EVIDENCE :
Chioma mu ee chioma
2026-09-28 13:50:52
2
MYSTERY 🔥🔥🔥 :
Emi awon woli[Fire][Fire]
2026-09-28 10:51:37
3
perry page :
moti goke ten ten
2026-09-28 12:20:30
1
ERIOLUWATOBILOBA SCF🤍☦️ :
Lori oke jordani la pe mi🙇♀️🕎
2026-09-29 09:12:55
1
Boluwajide :
Emi awon woli, Ipa re ga opo
2026-09-28 12:19:17
2
Olubunmi🥰 :
Oluwa mi yoo dide ninu ogo re, amunu mi dun ayi igba mi pada si rere, awo mi l'ewu ogo abo aso Egan kuro, Oluwa nitori temi oooooo.
Edumare jah Jehovah oba onibu ore, mo mu ope mi wa fun oo, mo wa jewo ore ree..........................
Baba o ku ise oo, Jesu o kuse oo
Olorun agbalagba, oba adani ma gbagbe eni o ku ise
2026-10-01 11:07:10
3
tobiana :
naja ti su mi mo felo si america
2026-09-28 15:18:45
2
Oluwanifemi Ishorlar :
ejide omo ogun gbala gbe oruko jesu ga fun ojo unla tani looni 😊😊😊
2026-10-01 20:25:56
1
OLU B :
Moti goke Tete oluwa ma je n jabo
2026-09-29 19:41:14
2
GIF | UGC Creator 🌸🦋✝️ :
omo oba ma mikan, omo oba masojo
omo oba magbagbe ooo
2026-09-29 11:02:32
2
🦋🌸Arewamhi 🌸🦋 :
jesu mi mo oun ti yo sehy
Jesu mi mo to yo sehy taye mi yo fi dara
2026-10-01 21:09:35
1
Mhiznikeh🥰 :
Omo oba mamaikan omo oba ma shojo
2026-09-29 10:02:57
1
Enioba :
igbagbo, ireti , ileri ti ko kipe ,ileri to Tete n ja sayo...,.
2026-09-30 17:16:18
1
m💊um❣️cy abigail 🥰💊💊med 💞 :
amin by bbo
2026-09-29 11:42:09
1
oluwatoyin foods❤️❣️ :
oluwa mi yo dide ninu ogo re amunu mi dun ayigba mi pada si rere awo mi lewu ogo abo aso Egan kuro oluwa mi yo dide nitori temi ooo oo oooo ooo 🙏🙏🙏
2026-09-28 12:22:02
3
Remilekunara🎙 :
Ipinle ti jesu fi lile leyi
2026-09-29 23:40:59
3
Adekunle De Light :
ojo agbarana ti osan doru tasojo mimo kalee ira meje loyo ni oke orun awon eye won ke luli
awon eye ke luli.. luli ore ofe irawo meje to yo ni oke orun awon ke luli
2026-09-29 15:05:07
1
To see more videos from user @yemidrey, please go to the Tikwm
homepage.