Aguntan ti o ba Aja rin yio je igbe. A kii tori gbigbo ka pa Aja, a kii tori kikan ka pa Agbo, a kii tori werewere ka pa obuko. Aja ti o ba maa sonu ko ni gbo fere Ode. Ala ti Aja ba la inu Aja ni ngbe. Ti Aja ba ni eni lehin a pa Obo. Ti Aja ba nsinwin a mo oju olowo re.
2026-10-28 06:30:25
4
SHARAFA DAN 777 :
**Ta lonjeun taja njuru
**Aja to ma sonu ko ngbo fere olode
**Ogidan oni se a gerun kaja debe lo gerun.
2026-10-30 00:59:02
3
badejoe :
Ajá to bá wọ'lé ẹkùn, á f'ẹ̀jẹ̀ wẹ̀.
2026-10-25 15:32:10
4
Fẹ́mi Adéyẹmí :
Ajá ìwòyí ló mọ Oworo ìwòyí lé
2026-10-25 16:00:14
3
Neotoyinshots :
A yan gbe aja dun, sugbon ki laa je ki aja to gbe
2026-10-27 09:58:54
2
hashimiu mistura abike :
The dogs in my next house are also watching my house ooo. Won roro titi won ṣọ ojulemeji [Tears of joy]
2026-10-28 09:52:16
1
MORADESCO@11 :
🌹🌹Aja ti yoo Sonu, koni gbo fere Olode!..
2026-10-26 11:36:32
2
gidexofdynamite :
Àgùntàn tó bá b'ájá rìn, á ję'gbęé
2026-10-25 15:44:30
3
adeyinkaadegbayibi :
Bi aja ba lẹni leyin, yoo pa ọbọ
2026-10-25 14:41:44
2
Kumasi 78 :
Agba Aja kii b'awo je
2026-10-26 08:32:44
2
jacobojiwnu :
ki aja ri egun ko magbo gbogbo ara aja ko logba
2026-10-27 08:39:30
1
Tosin Aniyikaye :
Aja Toyo kii ba aiyo sere
2026-10-25 14:52:54
2
BIG_ARINZO🇳🇬 🇨🇦 :
Aja toba leni leyin yopobó … 😹
2026-10-28 14:35:04
1
Tee-A :
Ere t’aja f’ogun odun sa, irin faaji ni f’esin
2026-10-25 14:40:18
2
Tosin Aniyikaye :
Taja ba nsiwin, a Maa moju ina
2026-10-25 14:53:28
2
Israely :
Aja iwoyi, lo mo ehoro iwoyi le
2026-10-28 08:08:04
1
🌻🌻 Saberedowo1 🌻🌻 :
Baja balẹni leyin yopọbọ
2026-10-28 06:08:01
1
Tosin Aniyikaye :
Taja ba Leni Lenin a pobo
2026-10-25 14:52:19
1
IRIRI :
aja to ri to njuru to tun ri ni to igbo o ye ka fura
2026-10-28 08:40:32
1
herbay apala :
kin shoju aja ayi jeun sun ekun
2026-10-31 11:27:43
0
Emperor :
Baja ba n síwín ó yę kó mojú iná
2026-10-31 15:01:32
0
Akarigidi :
Aja kii buru titi ki o ma m'oju olowo re.
2026-10-30 22:27:26
0
To see more videos from user @chrisnoble00, please go to the Tikwm
homepage.