@iretimbe.love: AGBÁRA ỌLỌ́RUN KÒ LÓPIN 🔥🙏 Ọba Ọ̀run àti Ayé ni Ọlọ́run, agbára Rẹ̀ sì ga ju gbogbo agbára lọ. Kò sí ohun tí kò lè ṣe, ìjọba Rẹ̀ sì wà títí láé. Níbi tí agbára ènìyàn bá ti dópin, níbẹ̀ ni agbára Ọlọ́run ti máa ń farahàn! Kò sí ẹni tó ga ju Ọba Ọ̀run àti Ayé lọ! #AgbaraOlorun #ObaOrunAtiAye #OlorunAlagbara #IretiMbe

ÌRÊTÍ MBẸ
ÌRÊTÍ MBẸ
Open In TikTok:
Region: BJ
Monday 26 October 2026 18:08:47 GMT
2783
180
4
41

Music

Download

Comments

olanireti.1
Ọ̀LÁNÍRÈTÍ :
gloire à Dieu
2026-10-26 18:22:12
1
kolade412
OLUWA KOLADE :
ògo ní fún ọlọrun
2026-10-26 19:06:38
1
olanireti.1
Ọ̀LÁNÍRÈTÍ :
OLUWA ọba àwọn ọba
2026-10-26 18:22:39
0
agbaraadura2
AGBARA ADURA :
[Cœur rouge][Cœur rouge][Cœur rouge]
2026-10-27 05:46:13
0
official_omowumi3
ỌMỌ WÙMÍ :
❤️❤️❤️
2026-10-28 00:06:45
1
To see more videos from user @iretimbe.love, please go to the Tikwm homepage.

Other Videos


About