@chiefifawande1: Ninu iseda ati ogun ibile Yoruba, apapo Ayan (kokoro ayan tabi ewe ayan/ayan ilegbe), Epo Obo, ati Ose Dudu jẹ nkan pataki ti a nlo fun Asina (lati la ona owo), Atude (lati tu ide kuro lara), ati Eyonu (lati rọ awon agbalagba tabi ota l'ọkan).