@imo.lagba.herbal02backup: GBOLOHUN RẸ LEYI:- AFẸ́FẸ́LẸ́LẸ́ tí ń fẹ́ lọ sí Ilé Olókun, má jẹ́ kí n bá wọn ráhùn Ajé Owó ńlá mọ́, ẸFÙFÙLẸ̀LẸ̀ tí ń fẹ́ lọ sí Ilé Ọlọ́sà, má jẹ́ kí n bá wọn ráhùn Ajé Owó ńlá mọ́, ÒJÌJÌ MÉJÌ tí ń sáré lọ sí Ilé Elédùmarè, má jẹ́ kí n bá wọn ráhùn ohunkóhun, Nítorí pé ÌṢÁWÙRÚ kì í ráhùn Omi, TIGITỌ̀PẸ̀ ní í ṣe Àánú ÀFỌ̀MỌ́, Ọmọ Eku kì í ráhùn Ìrun, Ọmọ Ẹyẹ kì í ráhùn Ìyẹ́, Ọmọ Ejò kì í ráhùn Ìrù, Ẹ má ṣe jẹ́ kí n ráhùn Owó ńlá mọ́ láyé mi. ÀDÚRÀ
HRM Imo lagba herbal02-IFACASH
Region: NG
Sunday 15 November 2026 18:02:43 GMT
Music
Download
Comments
OTUNBA :
Did you have it for sale sir
2026-11-15 18:19:11
0
marfattyender :
Thanks Sir Okunrin Eledua Eni Damu Lagbara Eledua Oba Mi Oke ☝️
2026-11-15 18:25:48
0
To see more videos from user @imo.lagba.herbal02backup, please go to the Tikwm
homepage.