@imo.lagba.herbal02backup: Replying to @hollad farms and agribusiness AFẸ́FẸ́LẸ́LẸ́ TÍ Ń FẸ́ RÒKÙN GBÉ OWÓ NLÁ WÁ FÚN MI, ÈFÙFÙLẸ̀LẸ̀ TÍ Ń FẸ́ LỌ̀SÀ GBÉ OWÓ NLÁ TỌ̀ MÍ WÁ, ÌRÁN ÌṢÁWÙRÚ KÌ Í RÁHÙN OMI, ÀTI IGI ÀTỌ̀PẸ̀ NÍ Í ṢÀÁNÚ FÁFỌ̀MÓ NÍGBÓ, ÒJÒJÒ KÌ Í Ṣ'OWÓ KÓ MỌ́NÀJÀ, MO TÍ KÀN ÀPÓTÍ ÌRÓKÒ SÍLẸ̀ F'ÀJÉ, K'ÀJÉ OWÓ NLÁ WÁ JOKÒÓ TÍ MÍ, A máa dá lé lórí Ọṣẹ yìí, Ẹ̀jẹ̀ Màlúù ni a máa fi pò mọ́ Ọṣẹ èyí tí a bá nífẹ̀ẹ́ sí.
HRM Imo lagba herbal02-IFACASH
Region: NG
Wednesday 18 November 2026 15:35:58 GMT
Music
Download
Comments
FACTB :
God bless you sir as you dey take your time to give us work, thank you sir ♥️
2026-11-18 15:55:35
0
Ola iLu :
this is another bangers thank you so much
2026-11-18 16:05:44
0
Thousand 01 :
adupe pupo baba
ola yi atun Bo ma lekun si amin 🙏🙏
2026-11-18 17:43:36
0
👑Omo Balogun 👑 :
baba ti aobari odo iron nko
se alegun ninu odo igi
2026-11-18 16:41:25
0
To see more videos from user @imo.lagba.herbal02backup, please go to the Tikwm
homepage.