@ifasola..1: Ìwúre (prayer) ~ "Olodùmare àwa omo re dé Olodumare we, the children have come Adé látì wá gba ìre tiwa, We have come to receive our Blessings for today Asin ńbè o lórúko odù mérìndínlógún We ask in the name of all the 16 major odù Ki o gbó ìre tòni yi That you should listen to the prayer of the day Bi o bá gbo ki o múu şę When you hear our prayers, please grant our request Ki o máa śo Baba wa Protect our Fathers Ki o máa śo Ìyá wa Protect our Mothers Ki o máa śo Aya tabi Oko wa Protect our Wives or Husbands Ki o máa śo Omo wa Protect our Children Ki o máa śo Alàbàá gbélé áti òré wa Protect our Neighbors and Friends Titi tófi mó ibi ti ani ęni dé And extend your protection to all our well-wishers Pàápàá àti àwon mòlébí wa Most especially our relatives Afi olójó óni bè ó We ask in the name of the Òrisà that rules today Ki o fi yè dénú For you to BE mindful of what we are doing Ki o fi yè dékùn For you to BE mindful of all our proceedings Ki o fi yè dé gbogbo ara For you to BE mindful of all our generalities Bàbá awa Omo re là ń pè ó Father, we the children are calling upon you...." Asé🙏 Àború, Àboyè, Àbosíse #fyp #foryou #trendingvideo #unitedstates #Ifa