@reedollar13: Olódùmarè, Ọba tó ń jọba láìlópin, mo dúpẹ́ fún ẹ̀mí àti oore-ọ̀fẹ́ Rẹ lórí ayé mi. Bí mo ṣe jí lónìí, kí ìbùkún jí pẹ̀lú mi. Kí ire gbogbo wọlé sí ayé mi. Kí ibi àti ìbànújẹ́ jìnnà sí mi. Kí ọ̀nà tí mo bá gbà lónìí jẹ́ ọ̀nà àṣeyọrí. Kí ọwọ́ mi má ṣe ṣófo. Kí iṣẹ́ ọwọ́ mi má bàjẹ́. Kí àwọn olùrànlọ́wọ́ mi má ṣe sùn. Kí ẹni tí yóò gbé mi ga rí mi lónìí. Kí gbogbo ohun rere tí mo ti ń retí di òtítọ́. Orí mi, má ṣe gbàgbé mi. Ayànmọ́ mi, má ṣe ta mí sílẹ̀. Àṣẹ àwọn òbí mi, ẹ má ṣe jẹ́ kí n ṣìnà. Kí ọjọ́ mi parí ní ayọ̀, àlàáfíà àti ìṣẹ́gun. Àṣẹ! Àṣẹ!! Àṣẹ!!! Ọlọ́run, jẹ́ kí òní dára ju àná lọ. Àmín. ❤️ #AduraOwuro #YorubaPrayer #MorningPrayer🌴🐚🌴🍃🍂🍂🐚🌴🐚🍃
🌴ÁĎÍŚÁ ĎĆ💚🌴
Region: NG
Thursday 26 November 2026 07:55:41 GMT
Music
Download
Comments
There are no more comments for this video.
To see more videos from user @reedollar13, please go to the Tikwm
homepage.