@ifasola..1: Ìwúre (prayer)" ~ ~ "Olodùmare àwa omo re dé Olodumare we, the children have come Adé látì wá gba ìre tiwa, We have come to receive our Blessings for today Asin ńbè o lórúko odù mérìndínlógún We ask in the name of all the 16 major odù Ki o gbó ìre tòni yi That you should listen to the prayer of the day Bi o bá gbo ki o múu şę When you hear our prayers, please grant our request Ki o máa śo Baba wa Protect our Fathers Ki o máa śo Ìyá wa Protect our Mothers Ki o máa śo Aya tabi Oko wa Protect our Wives or Husbands Ki o máa śo Omo wa Protect our Children Ki o máa śo Alàbàá gbélé áti òré wa Protect our Neighbors and Friends Titi tófi mó ibi ti ani ęni dé And extend your protection to all our well-wishers Pàápàá àti àwon mòlébí wa Most especially our relatives Afi olójó óni bè ó We ask in the name of the Òrisà that rules today Ki o fi yè dénú For you to BE mindful of what we are doing Ki o fi yè dékùn For you to BE mindful of all our proceedings Ki o fi yè dé gbogbo ara For you to BE mindful of all our generalities Bàbá awa Omo re là ń pè ó Father, we the children are calling upon you...." Asé🙏 Àború, Àboyè, Àbosíse #fyp #viral #creatorsearchinsights #unitedstates #foryou

🦋𝐈𝐅𝐀𝐒𝐎𝐋𝐀🦋
🦋𝐈𝐅𝐀𝐒𝐎𝐋𝐀🦋
Open In TikTok:
Region: NG
Friday 27 November 2026 08:43:33 GMT
1582
323
9
33

Music

Download

Comments

oluwabusuyimii
Mr CoolBREATHE :
Asheeee wa
2026-11-28 07:00:42
0
victor.ojo87
Jason Kincaid :
Àsè Èdùmàrè 🙌🏽🤲🏽🙏🏽‼️
2026-11-27 17:11:33
3
chris_stoner
Chris_stoner 💫🦅🌎 :
ASE
2026-11-28 08:09:43
1
wharley_kz
Wharley :
ASE Edumare 🙏
2026-11-28 06:36:40
0
amonpeamunututu
Amonpe Amunututu ❤️❤️❤️❤️ :
Ase o
2026-11-28 08:40:13
0
shadowfashiondesign
SHADOW FASHION DESIGNER 🇳🇬✂️ :
ASEeeeee
2026-11-28 07:07:08
0
yewandea1
OMIDARALARA......... :
Ase
2026-11-28 12:09:51
0
abdulrahmanadesil
abdulrahmanadesil :
Ase oooo
2026-11-28 05:13:06
0
ewatomi.babee
AJE 🧜🪽 OLOKUN 🧜🪽🪽 :
🙏🙏🙏
2026-11-28 10:21:41
0
To see more videos from user @ifasola..1, please go to the Tikwm homepage.

Other Videos


About